ASMN Ogun State Headquarter
AGBEKOYA SOLIDARITY MOVEMENT OF NIGERIA
Motto: ILE YIO GBE WA
NATIONAL HEADQUARTER: Olorunda Ogunso
We celebrate your victory Anthony Joshua
26/02/2024
Èyíinì iṣẹlẹ abàmì àti kayeefi ńláǹlà tí ó sele ni ilu Olodo ijoba ibile Odeda. Ọmọbìnrin tí an wo nínú agbára ẹ̀jẹ̀ ni àwọn onise láabi lupa mo le nínú ìyẹ̀wù tí wọn sì fọ lórí yáná yáná.
Èyíi mú kí àwọn ènìyàn ara àdúgbò pẹ̀lú ìyá ọmọbìnrin yí bugbe tá nígbà tí ìyà ọmọbìnrin yìí ṣe alaba pàdé ọmọkùnrin kan nínú igbó leba ilé tí ó sì jẹ wípé ẹni tí ó sún mọ́ ọmọbìnrin tí ó kú yìí daradara.
Èyíi mú kí àwọn ará ìlú pè eso alabo agbekoya Solidarity Movement of Nigeria lati wa fún iwadi òtítọ́ àti òdodo. Agbekoya àti àwọn dijo pàdé nibẹ tí wọn gbé òkú ọmọbìnrin yí lọ sí ilé igbokusi tí a fura si yí sii mbẹ ni ahamo àwọn olopa. Ìwádìí sí tẹ síwájú...
This is unbelievable incident that happened in a town called Olodo in Odeda Local government area.
A lady named Tope was gruesomely killed by a suspected boyfriend boyfriend.
This incident happened yesterday Sunday 26th of February 2024.
The suspect has been arrested in collaboration with police and he is in police custody also the deceased has been taken to the mortuary. Investigation is still on going.......
Click here to claim your Sponsored Listing.
Location
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Abeokuta
