Asiri tu! Gbajumo Wolii ijo Celestial tu asiri awon gbajumo Pasito to n s'egbe okunkun
*O so bi won se ran agbanipa si i
*O tun salaye nnkan t'awon eeyan ko mo nipa ijo Cele
Gbajumo Wolii ijo Celestial ilu Eko nni, Wolii Abraham Oyebamiji eni ti gbogbo eeyan mo si Baba Gethsemane ti tu asiri awon gbajumo Wolii kan, paapaa n'iluu Eko ti won wa ninu egbe okunkun pelu bi won se ran agbanipa lati pa a.
Awon gbajumo Wolii wo lo n se egbe okunkun? Kin ni won ran agbanipa loo pa Wolii Oyebamiji si? Bawo ni baba naa se bo mo awon agbanipa naa l'owo? Nje e mo pe oro yii de odo awon ijoba?
Nje e tie mo pe Wolii ijo CAC ni baba yii ko too wonu ijo Celestial? Bawo lo se wonu ijo Cele gan-an? Ki lo gbe e debe? Se loooto n'ijo Celestial maa n s'oogun? Ki lo de t'awon omo ijo Cele ki i wo bata l'ori a*o funfun won? Nje eyin mo asiri ipa nla ti oludasile ijo Celestial, Wolii S.B.J. Oshoffa ko l'ori awon gbajumo ijo to wa l'oju ona marose Eko s'Ibadan bii: Ridiimu, Mountain Of Fire, Deeper Life ati bee bee lo?
E wo o, oro po ninu iforowero yii o. E pade ekunrere re ninu iwe iroyin YORUBA TOOTO ati l'ori telifisan YORUBA TOOTO TV to wa l'ori ero ayelujara YouTube. E kuu ojulona o!
Otunba ola afeez
Otunba oladeni afeez nig Goldenlink properties nig ltd
26/08/2019
Not pass ALMIGHTY ALLAH
Have wourdafull dat
Good morrning very one
All the glory belong to almight GOD
Land for sale at kurudu 1000sqm 5m
Always Thank God ur life
Dnt be hurry in life
Let us have hope for change apc by hon oladeni afeez
Happy new month
Click here to claim your Sponsored Listing.
Location
Category
Website
Address
Plot 239 Muhamedu Buhari Way Centra Area Abuja
Abuja
