22/05/2019
Niun Aye Ogomi Gbodo Dide
Uun
22/05/2019
Omo ologo ni niun aye lagbara olohun adaniwaye ogo migbodo tan saye wola iun osu ti awa yi o ati gbogbo eyin olugbo mi niun ile yi
14/07/2017
Gbogbo eyin panapana ti ema npa ina ogo. ti iun omi ni yin ni, ti orile ni yin ni, tabi ti oju ofurufu ti e ngbe iun aye omo eniyan sise ibi, Ni oruko Olohun Imole Asiyin lowo ise niun aye mi ati ohun ti mo ni amin. ore mi bami so tie naa maroun si yio gba
Niun aye ogo mi gbodo dide kini oun ti aunpe ni ogo gan.ogo ni ipin rere ti Olohun adaniwaye pin fun enikokan ti o da lati se rere laye,ogo elomiran ama tan lati ibi oro siso,tabi kio tan lati ara iwa ti oni, tabi ishe,nitori ogo ki tan laisi ebun ore mi kin wani ebun re ti oni lati fi tan ina ogo re laye,nitoripe ohun gbogbo ti onilo ni ounbe ni IUN re ore mi odara fun e lati se awari EBUN re ki ogo re le dide LAYE.
In everyting with God
Click here to claim your Sponsored Listing.
Location
Category
Contact the business
Website
Address
Apete
Ibadan
